Home -- Yoruba -- 17-Understanding Islam -- 080 (The Bible says the Son is God)
This page in: -- Arabic? -- Bengali -- Cebuano -- English -- French -- Hausa -- Hindi -- Igbo -- Indonesian -- Kiswahili -- Malayalam -- Russian -- Somali -- Ukrainian -- YORUBA
Previous Chapter -- Next Chapter
17. Oye Islamu
IPIN KARUN: OYE MUSULUMI AWỌN ATAKO SI IHINRERE
ORÍ 13: ÀWÒN ATAKO MUSULMI SI KRISTIENI
13.3. Awọn atako si Mẹtalọkan
13.3.2. Bíbélì sọ pé Ọmọ ni Ọlọ́run
- “Ọlọ́run àti Olùgbàlà wa Jésù Kristi.” (2 Pétérù 1:1)
- “duro de ireti ibukun wa, ifarahan ogo Ọlọrun nla ati Olugbala wa Jesu Kristi.” (Titu 2:13)
- "Ṣùgbọ́n nípa Ọmọ ni ó sọ pé, ‘Ìtẹ́ rẹ, Ọlọ́run, wà títí láé àti láéláé, ọ̀pá aládé ìdúróṣinṣin ni ọ̀pá aládé ìjọba rẹ." (Hébérù 1:8)