Home -- Yoruba -- 20-For Readers of the Qur'an -- 062 (The Blessings of Marriage)
Previous Chapter -- Next Chapter
20. Fun awon Oluka Kurani
IWE 6 - ṢE O MỌ OGBON KRISTI?
3. Ibukun Igbeyawo
“27 Ẹ̀yin ti gbọ́ bí a ti wí pé, ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ ṣe panṣágà’; 28 Ṣùgbọ́n mo wí fún yín pé, olúkúlùkù ẹni tí ó bá wo obìnrin kan láti ṣe ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ sí i, ó ti bá a ṣe panṣágà nínú ọkàn rẹ̀ ná.” (Mátíù 5:27-28)
“5 Ó ní, ‘Nítorí ìdí yìí ọkùnrin yóò fi baba àti ìyá rẹ̀ sílẹ̀, yóò sì fà mọ́ aya rẹ̀; àwọn méjèèjì yóò sì di ara kan’. 6 Nitori naa wọn ki i ṣe meji mọ, ṣugbọn ara kan. Nítorí náà, ohun tí Ọlọ́run ti so pọ̀, kí ẹnikẹ́ni má ṣe yà á sọ́tọ̀.” (Mátíù 19:5-6)