Home -- Yoruba -- 20-For Readers of the Qur'an -- 074 (The Deceit of Riches)
Previous Chapter -- Next Chapter
20. Fun awon Oluka Kurani
IWE 6 - ṢE O MỌ OGBON KRISTI?
15. Ẹ̀tàn Ọọ̀rọ̀
“23 Jesu wi fun awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ pe, Lotọ ni mo wi fun nyin, o ṣoro fun ọlọrọ̀ lati wọ ijọba ọrun. 24 Mo tún sọ fún yín pé, ó rọrùn fún ràkúnmí láti gba ojú abẹ́rẹ́ kọjá, ju kí ọlọ́rọ̀ wọ ìjọba Ọlọ́run lọ.’ 25 Nígbà tí àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ gbọ́ èyí, ẹnu yà wọ́n gidigidi. ó sì wí pé, ‘Ǹjẹ́ ta ni ó lè là?’ 26 Jésù sì wò wọ́n, ó sì wí fún wọn pé, ‘Lọ́dọ̀ ènìyàn ni èyí kò ṣe é ṣe, ṣùgbọ́n lọ́dọ̀ Ọlọ́run ohun gbogbo ṣeé ṣe.’” (Mátíù 19:23-26)