Home -- Yoruba -- 20-For Readers of the Qur'an -- 081 (The Parable of the Mustard Seed)
Previous Chapter -- Next Chapter
20. Fun awon Oluka Kurani
IWE 6 - ṢE O MỌ OGBON KRISTI?
22. Òwe Irugbin eweko
“31 Kristi tún fi òwe mìíràn fún wọn pé, ‘Ìjọba ọ̀run dà bí èso músítádì, tí ọkùnrin kan mú, tí ó sì fúnrúgbìn sí oko rẹ̀; 32 Èyí kéré ju gbogbo irúgbìn yòókù lọ; ṣùgbọ́n nígbà tí ó bá dàgbà tán, ó tóbi ju àwọn ewéko ọgbà lọ, ó sì di igi, tí ó fi jẹ́ pé àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run wá, wọ́n sì tẹ́ ìtẹ́ sínú ẹ̀ka rẹ̀.’” (Mátíù 13:31-32)