Home -- Yoruba -- 20-For Readers of the Qur'an -- 083 (The Parables of the Hidden Treasure and of the Priceless Pearl)
Previous Chapter -- Next Chapter
20. Fun awon Oluka Kurani
IWE 6 - ṢE O MỌ OGBON KRISTI?
24. Awọn owe ti awọn pamọ iṣura ati ti Pearli ti ko ni idiyele
“44 Ìjọba ọ̀run dàbí ìṣúra tí a fi pamọ́ sínú pápá, èyí tí ọkùnrin kan rí tí ó sì fi pamọ́; inú rẹ̀ sì dùn, ó lọ tà gbogbo ohun tí ó ní, ó sì ra oko náà. 45 Lẹ́ẹ̀kan sí i, ìjọba ọ̀run dà bí oníṣòwò kan tí ń wá àwọn péálì àtàtà, 46 nígbà tí ó sì rí péálì kan tí ó níye lórí, ó lọ, ó sì tà gbogbo ohun tí ó ní, ó sì rà á.” (Mátíù 13:44-46)