Home -- Yoruba -- 20-For Readers of the Qur'an -- 092 (The Sign of Jonah)
Previous Chapter -- Next Chapter
20. Fun awon Oluka Kurani
IWE 6 - ṢE O MỌ OGBON KRISTI?
33. Àmì Jona
“39 O si dahùn o si wi fun wọn pe, Iran buburu ati panṣaga nfẹ àmi; ṣugbọn a kì yio fi àmi kan fun u bikoṣe àmi Jona woli; 40 Nítorí gẹ́gẹ́ bí Jónà ti wà nínú ikùn ẹja ńlá fún ọ̀sán mẹ́ta àti òru mẹ́ta, bẹ́ẹ̀ náà ni Ọmọ-ènìyàn yóò gbé ọ̀sán mẹ́ta àti òru mẹ́ta ní àárín ilẹ̀ ayé.” (Mátíù 12:39-40)