Home -- Yoruba -- 20-For Readers of the Qur'an -- 097 (The Signs of Christ in His Glorious Coming)
Previous Chapter -- Next Chapter
20. Fun awon Oluka Kurani
IWE 6 - ṢE O MỌ OGBON KRISTI?
38. Awon ami Kristi N‘nu Wiwa Ogo Re
“29 Lẹsẹkẹsẹ lẹhin ipọnju ọjọ wọnni, õrùn yoo ṣokunkun, oṣupa kì yio si tan imọlẹ rẹ̀, awọn irawọ̀ yio si jábọ́ lati ọrun wá, a o si mì awọn agbara ọrun, 30 ati lẹhin na àmi ọrun yio mì; Ọmọ ènìyàn yóò farahàn ní ọ̀run, nígbà náà ni gbogbo àwọn ẹ̀yà ayé yóò sì ṣọ̀fọ̀, wọn yóò sì rí Ọmọ-Eniyan tí ń bọ̀ lórí ìkùukùu ọ̀run pẹ̀lú agbára àti ògo ńlá. 31 Yóo sì rán àwọn angẹli rẹ̀ jáde pẹlu fèrè ńlá, wọn óo kó àwọn àyànfẹ́ rẹ̀ jọ láti orígun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin. (Mátíù 24:29-31)