4.01 - ÌFÁÀRÀ: Gbogbo Ìṣepàtàkì Òfin Mẹ́wàá
Laipẹ àwọn èrò ọkọ̀ òfurufú tí ọ ń lọ láti Delhi sí Sinafar ni Kashmir ko ni pẹẹ rí titobi ìsesí òkè oníyinyin Himalaya tí ó yọ láti ibi pẹtẹlẹ ariwa Indian. Àwọn afonifojì tí ó ji àti àwọn tí kò jì ni ó sì pín àwọn òkè sonso niya. Awosanmo/ìkùùku, si bọ tẹ̀ntérí àwọn ọ̀kè. Àwọn oníràn oníwọ̀n ẹgbẹrun mejọ mita sì bọ àwọn kékéèké tí ó ga níwọ̀n ẹgbẹrun marun mita.
Lẹ́yìn tí àwọn èrò bá tí gunlẹ̀ sì Sinagar tàn, àwọn onítara ẹsìn àti asa ni àwọn alejọ yìí yóò kọkọ padé. Adaludapò àwọn Hindu, Buddhist, Júù, Kírisítẹ́nì, Mùsùlùmí àti àwọn tí kò gbà pé Ọlọ́run wá ni ó ń gbé papọ̀ níbi. Bẹ́ẹ̀ni ni àwọn Tempìilì, Sóòsì, Mosáàlásì àti patako ìkéde tàbí ipolungo ń pé akíyèsì àwọn ẹ̀rọ̀. Orílẹ̀dè marun otòótọ́ ni ó korajọpọ̀ sí ibi yìí. Àwọn ni India, Pakistan, Afghanistan, Russia àti China - ẹnikẹ́ni tí ó bá ń rín irinàjọ kọja nínú àwọn ilù àti abule. Kashimiri tí ó sì ń bá àwọn olúgbé ibẹ sọrọ yóò sì ni ìmọ̀lára atẹ́gun òdì àti ìpayà.
Ní tọ̀ótọ́, ogun abele tí ó le ni ó tí ja afonifoji darádará yi li 1991. Òfin àti asa awaọn èsìn agbaiyé tí ó lagbára jù àti afojusùn ẹtọ òsẹ̀lú àwọn ijọba agbàyé safihàn gbedeke tí ó tẹ́nílọ́rùn bí òkè Himalayan. Sùgbọ́n oríṣiríṣri akọ́sílẹ̀ àti àwọn òfin ẹ̀sìn fí aye sílẹ̀ fún àwọn díẹ̀ tí ó ń sáájú àwọn iyoku bí òkè giga Himalaya.