Home -- Yoruba -- 20-For Readers of the Qur'an -- 067 (Is Your Eye Clear?)
Previous Chapter -- Next Chapter
20. Fun awon Oluka Kurani
IWE 6 - ṢE O MỌ OGBON KRISTI?
8. Ojú rẹ ha mọ́?
“22 Ojú ni àtùpà ara; Nítorí náà bí ojú rẹ bá mọ́, gbogbo ara rẹ ni yóò kún fún ìmọ́lẹ̀. 23 Ṣùgbọ́n bí ojú rẹ bá burú, gbogbo ara rẹ yóò kún fún òkùnkùn. Nítorí náà bí ìmọ́lẹ̀ tí ó wà nínú rẹ bá jẹ́ òkùnkùn, báwo ni òkùnkùn náà ti pọ̀ tó!” (Mátíù 6:22-23)