Home -- Yoruba -- 20-For Readers of the Qur'an -- 068 (How Can You Find Rest For Your Soul?)
Previous Chapter -- Next Chapter
20. Fun awon Oluka Kurani
IWE 6 - ṢE O MỌ OGBON KRISTI?
9. Bawo ni O Ṣe Le Wa Isinmi Fun Ọkàn Rẹ?
“28 Ẹ wá sọ́dọ̀ mi, gbogbo ẹ̀yin tí ó rẹ̀, tí wọ́n sì di ẹrù wuwo lọ́rùn, èmi ó sì fún yín ní ìsinmi. 29 Ẹ gba ajaga mi si ọrùn nyin, ki ẹ si kọ́ ẹkọ́ lọdọ mi: nitori onipẹlẹ ati onirẹlẹ ọkan li emi; ẹnyin o si ri isimi fun ọkàn nyin. 30 Nítorí àjàgà mi rọrùn, ẹrù mi sì fúyẹ́.” (Mátíù 11:28-30)