Home -- Yoruba -- 20-For Readers of the Qur'an -- 087 (Christ's Prophecy about His Suffering and Resurrection)
Previous Chapter -- Next Chapter
20. Fun awon Oluka Kurani
IWE 6 - ṢE O MỌ OGBON KRISTI?
28. Àsọtẹ́lẹ̀ Kírísítì nípa Ìjìyà àti Àjíǹde Rẹ̀
“17 Bí Jésù ti fẹ́ gòkè lọ sí Jerúsálẹ́mù, ó kó àwọn ọmọ ẹ̀yìn méjìlá náà sẹ́gbẹ̀ẹ́ kan, ó sì sọ fún wọn ní ọ̀nà pé: 18 ‘Wò ó, àwa ń gòkè lọ sí Jerúsálẹ́mù; a o si fi Ọmọ-enia le awọn olori alufa ati awọn akọwe lọwọ, nwọn o si da a lẹbi ikú, 19 nwọn o si fi le awọn Keferi lọwọ lati fi ṣe ẹlẹyà, ati lati nà, ati lati kàn a mọ agbelebu. Ati ni ijọ kẹta yio si jinde.’” (Matiu 20: 17-19)