Home -- Yoruba -- 17-Understanding Islam -- 029 (Christ’s miraculous conception)
This page in: -- Arabic? -- Bengali -- Cebuano -- English -- French -- Hausa -- Hindi -- Igbo -- Indonesian -- Kiswahili -- Malayalam -- Russian -- Somali -- Ukrainian -- YORUBA
Previous Chapter -- Next Chapter
17. Oye Islamu
IPIN KẸTA: LILOYE KRISTI MUSULUMI
ORI 6: KRISTI NINU ISLAMU
6.1. Oyun iyanu ti Kristi
A kà nínú Kuran bí Màríà ṣe lóyún Jésù nípa ìbẹ̀wò kan láti ọ̀dọ̀ áńgẹ́lì Jibril (Gébúrẹ́lì):
“Ati (apejuwe) Mariyama, ọmọbinrin Imrana, ẹni ti o pa amọ rẹ mọ, nitori naa A fọ sinu [aṣọ rẹ] nipasẹ Malaika Wa, O si gba ọrọ Oluwa rẹ gbọ ati ti awọn iwe-mimọ Rẹ, o si wa ninu awọn olufọkansin.” (Kur’an 66:12)
Qur’an commentator Ibn Kathir says:
“A si mimi sinu re (apakan aladani) nipase Ruh Wa, itumo, lati odo Malaika Jibril. Olohun ran Malaika Jibril si Mariyama, o si wa ba a ni irisi okunrin ni gbogbo ona. Olohun pa a lase pe ki o fe sinu aafo kan ti aso re ati pe èémi naa wọ inu rẹ̀ lọ lati inu ara-ara rẹ̀; Báyìí ni a ṣe bí Isa. (Ibn Kathir, Ọrọ asọye Al-Kur’an lori 66:12).